Darlington Nwokocha
Ìrísí
Darlington Nwokocha | |
---|---|
Sénátọ̀ tí ó ń sójú Abia Central | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2023 | |
Ààrẹ | Bola Tinubu |
Gómìnà | Alex Otti |
Vice President | Kashim Shettima |
Asíwájú | Theodore Orji |
Arọ́pò | Ginger Onwusibe |
Ọmọ ẹgbẹ́ House of Representatives for Isiala Ngwa North/Isiala-Ngwa South | |
In office 29 May 2015 – 29 May 2023 | |
Ààrẹ | Muhammadu Buhari |
Gómìnà | Okezie Ikpeazu |
Vice President | Yemi Osinbajo |
Ọmọ ẹgbẹ́ Abia State House of Assembly for Isiala Ngwa North | |
In office 29 May 2007 – 29 May 2015 | |
Ààrẹ | Umaru Musa Yar'Adua |
Gómìnà | Theodore Orji |
Vice President | Goodluck Jonathan |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Àsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ àmì ìdádúró-ọ̀rọ̀ sókí "{". 16 August 1967 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Labour Party |
Other political affiliations | People's Democratic Party (2017—2023) |
Darlington Nwokocha jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó jẹ́ asójú agbègbè Abia Central federal láti ọdún 2023.[1] Kí ó tó di Sénátọ̀, ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Ilé ìgbìmò asofin kékeré tí ó sójú Isiala-Ngwa North/Isiala-Ngwa South láàrin 2015 sí 2019. Nwokocha jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Abia State House of Assembly láàrin 2007 sí 2015.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Silas, Don (27 February 2023). "Election result: INEC declares LP's Nwokocha winner of Abia Central Senatorial seat". Daily Post. Retrieved 2 April 2023.
- ↑ "Hon. Darlington Nwokocha | Isiala Ngwa North/South Federal Constituency". National Assembly. Retrieved 2 April 2023.