Adolphe Muzito
Adolphe Muzito | |
---|---|
Alakoso Agba OOT ile Kongo | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 10 Osu Kewa 2008 | |
Ààrẹ | Joseph Kabila |
Deputy | Nzanga Mobutu Emile Bongeli Yeikolo Yaato Mutombo Bakafwa Nsenda |
Asíwájú | Antoine Gizenga |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1957? |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Egbe Lumumbisti Piparapo |
Adolphe Muzito (ojoibi 1957[1] in Gungu, Igberiko Kwilu) ni oloselu ara Kongo OOT lowolowo to je Alakoso Agba Orile-ede Olominira Toseluarailu ile Kongo. Muzito, omo egbe oloselu Egbe Lumumbisti Piparapo (PALU), teletele ti je Alakoso Isuna labe Alakos Agba Antoine Gizenga lati 2007 de 2008.
Muzito, to wa lati Gungu, Igberiko Kwilu, je onimo oro-okowo.[1] Ninu ijoba to je yiyansipo ni ojo 5 Osu Keji 2007, Muzito je mimupo bi Alakoso Isuna.[2] Leyin ti Gizenga, to je olori PALU, kosesile bi Alakoso Agba ni 25 Osu Kesan 2008 fun idi to jemo ojo-ori ati ilera, Muzito je yiyansipo latowo Aare Joseph Kabila lati ropo Gizenga ni 10 Osu Kewa 2008.[1]
Ijoba Muzito bere ise ni ojo 26 Osu Kewa 2008. Yato si Muzito funra re, ijoba re ni eniyan 53: awon igbakeji alakoso agba meta, awon alakoso 36, ati awon igbakeji alakoso 14.[3] Opo awon eniyan inu ijoba yi wa lati Egbe Araalu fun Itunleko ati Oseluarailu, beesini Kabila pe bi "egbe ti ise won je lati se abo ati itunleko".[4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 "DR Congo president names new prime minister: report", AFP, 10 October 2008.
- ↑ "Le nouveau gouvernement de la République Démocratique du Congo est constitué", Afrik.com, 6 February 2007 (Faransé).
- ↑ "Publication de la liste des membres du nouveau gouvernement congolais" Archived 2009-12-03 at the Wayback Machine., PANA (africanmanager.com), 27 October 2008 (Faransé).
- ↑ "Fresh fighting poses challenge to new DRCongo government", AFP, 27 October 2008.