Aymara
Ìrísí
Àpapọ̀ iye oníbùgbé |
---|
2.0 million |
Regions with significant populations |
Bolivia (1,462,286)[1] |
Èdè |
Ẹ̀sìn |
Catholicism adapted to traditional Andean beliefs |
Ẹ̀yà abínibí bíbátan |
Aymara
Omo egbé Quechumaran ni Aymara. Quechumaran fúnrarè náà jé omo egbé fún àwon èdè Andea-Equatorial. Àwon tí ó ń so àwon èdè wònyí lé díè ní mílíònù méjì (2.2.million). Púpò nínú àwon tí ó ń so wón wà ní Bolivia (1.8 million) ó dín díè ní mílíònù méjì. Wón tún ń so àwon èdè wònyí ní Peru àti apá kan Argentina. Àkótó Rómáànù ni wón fi ń ko ó sílè. Ní ìgbà kan rí, Aymara jé èdè kan tí ó se pàtàkì ní ààrin gbùngbùn Andes tí wón jé apá kan Énípáyà Inca (Inca Empire)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Bolivia National Census 2001, figures listed in Ramiro Molina B. and Javier Albó C., Gama étnica y lingüística de la población boliviana, La Paz, Bolivia, 2006, p 111.
- ↑ Peru National Census 1993, figures listed in Andrés Chirinos Rivera, Atlas Lingüístico del Perú, Cuzco: CBC, 2001.
- ↑ Chile National Census 2002, figures cited in Bilingüismo y el registro matemático aymara