Fartuun Adan
Ìrísí
Fartuun Adan فرتون آدن | |
---|---|
Adan in 2015 | |
Ọjọ́ìbí | Somalia |
Iṣẹ́ | Activist |
Title | Executive Director of the Elman Peace and Human Rights Centre |
Olólùfẹ́ | Elman Ali Ahmed |
Àwọn ọmọ | 4: Almas, Ilwad and Iman |
Fartuun Abdisalaan Adan jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn ti ìlú Somalia. Òun ni adarí àgbà fún Elman Peace and Human Rights Centre.
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Adan dàgbà sí ìlú Somalia. Ó fẹ́ Elman Ali Ahmed, tó jẹ́ oníṣòwò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́mọnìyàn, tó ń rí sétò àlàáfíà.[1][2] Wọ́n sì jọ bí ọmọ mẹ́rin.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Nima Elbagir; Lillian Leposo (5 August 2013). "Rape and injustice: The woman breaking Somalia's wall of silence". CNN. Retrieved 8 February 2014.
- ↑ 2.0 2.1 "Documento - Somalia: Amnistia Internacional condena el asesinato de un pacifista". Amnesty International. Retrieved 9 February 2014.