Jump to content

James Gandolfini

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
James Gandolfini
Gandolfini in 2011
Ọjọ́ìbíJames Joseph Gandolfini, Jr.
(1961-09-18)Oṣù Kẹ̀sán 18, 1961
Westwood, New Jersey, U.S.
AláìsíJune 19, 2013(2013-06-19) (ọmọ ọdún 51)
Rome, Italy
Orúkọ mírànjósẹ́fù
Iṣẹ́Olòséré
Ìgbà iṣẹ́1987–2013
Olólùfẹ́Marcy Wudarski
(m. 1999–2002)
Deborah Lin
(m. 2008–2013, his death)
Àwọn ọmọ2
Websitehttps://en.m.wikipedia.org/wiki/James_Gandolfini

Ọmọ ilé-ìwé = Rutgers Ifáfitì-

New Brūnswik


James Joseph Gandolfini, Jr. (ojoibi Oṣù Kẹ̀sán 18, 1961 – Kẹfà 19, 2013) je osere ara Amerika. Fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi "Toni Sọ̀pránò" Alága àwon Ńsọmí tó jé Itálíán-Amẹ́ríkàní nínú eré HBO tí wọ́n pè ní "Awọn Sọ̀pránósì". Ogbẹ́ni Jákọ́bu Gàndólfínì jr. jẹ ẹ̀yẹ Emmy Mé̩ta, ẹ̀yẹ SAGA Márùn-ún, ẹ̀yẹ GGA ẹyọ kan. Ipa rẹ́ gẹ̀gẹ̀ bí "Toni Sọ̀pránò" tó̩ka si gẹ́gẹ́ bí Olósèré tí ó tóbi jù àti tó lọ́lá jùlọ nínú amóhùnmáwòrán wa.


Ògbẹ́ni Gàndólfínì pẹ̀lú gẹ́gẹ́ bi àgbàjọ ènìyàn ọ̀tún Virgil nínu eré True Romance (1993), lẹ́ftẹ́nántì Bọ́bì Douhertì nínu Krímsọ́n Tīde (1995), Kọ́nẹ́lì Wíńtà nínu The Lāst Kástù (2001), àti Alákoso ìlu Nēw Yọ̀rk nínu Thē Tákíng of Pẹ́lhàm 123 (2009). Awọn eré rẹ̀ míràn pẹ̀lú Gẹt Shọrti (1995), Whẹre the Wild Things Are (2009), Ẹnough Said (2013). Ọgbẹ́ni Gāndolfini gba ẹ̀yẹ Skreen Aktors Guild Award àti yíyàn Boston Sosiety of Film Kritiks Award fún olósèré tí ó sé àtìlẹyìn lẹ́yìn iku rẹ̀. Ní ọdún 2007, Ogbẹ́ni Gāndolfini

https://en.m.wikipedia.org/wiki/James_Gandolfini