Jump to content

Joseph Kabila

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Joseph Kabila
Kabila in 2016
4th President of the Democratic Republic of the Congo
In office
17 January 2001 – 24 January 2019
Acting: 17 January 2001 – 26 January 2001
Alákóso ÀgbàAntoine Gizenga
Adolphe Muzito
Louis Alphonse Koyagialo (Acting)
Augustin Matata Ponyo
Samy Badibanga
Bruno Tshibala
Vice PresidentAzarias Ruberwa
Arthur Z'ahidi Ngoma
Abdoulaye Yerodia Ndombasi
Jean-Pierre Bemba (2003–2006)
AsíwájúLaurent-Désiré Kabila
Arọ́pòFélix Tshisekedi
Senator for life
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
15 March 2019
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Joseph Kabila Kabange

4 Oṣù Kẹfà 1971 (1971-06-04) (ọmọ ọdún 53)
Fizi, Congo-Léopoldville
(now Democratic Republic of the Congo)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Party for Reconstruction and Democracy
(Àwọn) olólùfẹ́
Alma materMakerere University
People's Liberation Army National Defense University
Military service
AllegianceÀdàkọ:Country data DR Congo
Branch/serviceArmed Forces of the Democratic Republic of the Congo
RankMajor-general

Joseph Kabila Kabange (lasan bi Joseph Kabila; ojoibi 4 Osu Kefa, 1971), ni Aare ti Orile-ede Olominira Toseluarailu ile Kongo (OOTK) lati 2001 ti de 2019 . O bo si ori aga ni Osu Kinni odun 2001, ojo mewa leyin iku oloro to pa baba re Laurent-Désiré Kabila to ti je aare OOTK. Ni 27 Osu Kokanla 2006, Joseph Kabila je mimudaju bi Aare leyin to ti bori ninu idiboyan gbogbogbo ti Osu Keje 2006. Ni Oṣu Kẹwa Ọdun 2021, Joseph Kabila gbeja iwe-ẹkọ ayẹyẹ ipari ẹkọ rẹ ni University of Johannesburg. Iwe-oye oye oye nipa sayensi oselu ati ajosepo agbaye ni a fun ni ni ipari awọn ẹkọ rẹ ti o fi opin si ọdun marun.