Winston Churchill
Sir Winston Churchill | |
---|---|
Prime Minister of the United Kingdom | |
In office 26 October 1951 – 7 April 1955 | |
Monarch | George VI Elizabeth II |
Deputy | Anthony Eden |
Asíwájú | Clement Attlee |
Arọ́pò | Anthony Eden |
In office 10 May 1940 – 27 July 1945 | |
Monarch | George VI |
Deputy | Clement Attlee |
Asíwájú | Neville Chamberlain |
Arọ́pò | Clement Attlee |
Chancellor of the Exchequer | |
In office 6 November 1924 – 4 June 1929 | |
Alákóso Àgbà | Stanley Baldwin |
Asíwájú | Philip Snowden |
Arọ́pò | Philip Snowden |
Home Secretary | |
In office 19 February 1910 – 24 October 1911 | |
Alákóso Àgbà | Herbert Henry Asquith |
Asíwájú | Herbert Gladstone |
Arọ́pò | Reginald McKenna |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 30 Oṣù Kọkànlá 1874 Blenheim, Oxfordshire, England |
Aláìsí | 24 Oṣù Kínní 1965 (ọmọ ọdún 90) Hyde Park, London, England |
Resting place | St Martin's Church, Bladon, Oxfordshire, England |
Ọmọorílẹ̀-èdè | British |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Conservative (1900–1904, 1924–1964) Liberal (1904–1924) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Clementine Churchill |
Ẹbí | Pamela Harriman, daughter-in-law |
Àwọn ọmọ | Diana Churchill Randolph Churchill Sarah Tuchet-Jesson Marigold Churchill Mary Soames |
Residence | 10 Downing Street (official) Chartwell (private) |
Alma mater | Harrow School, Royal Military Academy Sandhurst |
Profession | Member of Parliament, statesman, soldier, journalist, historian, author, painter |
Winston Leonard Spencer-Churchill, KG, OM, CH, TD, PC, FRS (30 November 1874 – 24 January 1965) je oloselu ara Britani ti o gbajumo fun isolori re fun orílẹ̀-èdè Isodokan Ile-Oba ni asiko Ogun Agbaye Keji. O di Alakoso Agba Britani lati 1940 de 1945 ati lekansi lati 1951 deo 1955. Asiwaju pataki ati adoroso, Churchill tun je ogagun ni ise Adogun Britani, onitankiko, olukowe ati asona. Doni, ohun nikan ni he Alakoso Agba Britani to ba Ebun Nobel ninu Litireso, ati eni keji ti o je niyi bi Araalu Oniyi Isodokan awon Ipinle Amerika.
Nigba to wa nibise ajagun, Churchill kopa ninu ise ologun ni India, Sudan ati Ogun Boer Keji. O gbajumo gege bi afiroyinranse ogun ati awon iwe to ko lati sejuwe awon ohun ton sele. Bakanna o tun sise ni ibise Adogun Britani ni Ojuogun Apaiwoorun ninu Ogun Agbaye Akoko, nibi to tidari awon Eso 6th ti Royal Scots Fusiliers.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |