Roger Federer
Federer at the 2009 Wimbledon Championships | |
Orílẹ̀-èdè | Switzerland |
---|---|
Ibùgbé | Wollerau, Switzerland and Dubai, United Arab Emirates[1] |
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kẹjọ 1981 Basel, Switzerland |
Ìga | 1.85 m (6 ft 1 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 1998 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (one-handed backhand) |
Ẹ̀bùn owó | $76,541,427 |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 885–200 (81.57% in ATP World Tour and Grand Slam main draw matches, and in Davis Cup) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 77 (4th in the Open Era) |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (2 February 2004) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 7 (11 November 2013) |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | W (2004, 2006, 2007, 2010) |
Open Fránsì | W (2009) |
Wimbledon | W (2003, 2004, 2005, 2006, 2007, 2009, 2012) |
Open Amẹ́ríkà | W (2004, 2005, 2006, 2007, 2008) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje ATP | W (2003, 2004, 2006, 2007, 2010, 2011) |
Ìdíje Òlímpíkì | Silver medal (2012) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 120–80 (60% in ATP World Tour and Grand Slam main draw matches, and in Davis Cup) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 8 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 24 (9 June 2003) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | 3R (2003) |
Open Fránsì | 1R (2000) |
Wimbledon | QF (2000) |
Open Amẹ́ríkà | 3R (2002) |
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn | |
Ìdíje Òlímpíkì | Gold medal (Àdàkọ:OlympicEvent) |
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò | |
Hopman Cup | W (2001) |
Last updated on: 24 January 2013. |
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki | |||
Adíje fún Switzerland | |||
---|---|---|---|
Men's Tennis | |||
Wúrà | 2008 Beijing | Doubles | |
Fàdákà | 2012 London | Singles |
Roger Federer (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈfeːdəʁɐ]) (ojoibi 8 August 1981) je agba tenis ara Switsalandi to di Ipo No. 1 ATP mu fun rekodu ose 237 nitelentele lati 2 February 2004 de 18 August 2008.[2] Federer ti di ipo kinni mu fun apapo ose 285, to fi ose kan din si rekodu ose 286 ti Pete Sampras ni. Titi di 28 May 2012, ohun lo wa ni Ipo No. 3 Lagbaye. Federer ti gba ife-eye Grand Slam enikan awon okunrin ni igba 16 to je rekodu. O je ikan ninu awon okunrin atayo to gba gbogbo Grand Slam ati ikan ninu awon eniyan meta (pelu Andre Agassi ati Rafael Nadal) to seyi lori papa itayo otooto meta (papa alamo, onikoriko, ati olojulile). Ohun nikan ni okunrin atayo ninu tenis titi doni to de idopin idije Grand Slam kookan ni emarun o kerejulo ati idopin ikookan awon Idije ATP Masters 1000 mesesan. Opo awon olutuwo ere-idaraya, olugbewo tenis, ati awon atayo lowo ati tele gba pe Federer ni atayo tenis to gbokikijulo.[3][4][5][6][7][8][9]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Credit Suisse – Roger Federer, a Basel Boy Forever". Sponsorship.credit-suisse.com. Archived from the original on 2013-05-30. Retrieved 2013-01-22.
- ↑ "Profile: Roger Federer – The greatest ever". CNN. 6 July 2009. Archived from the original on 30 April 2011. https://web.archive.org/web/20110430102905/http://edition.cnn.com/2009/SPORT/07/04/roger.federer.profile.wimbledon/index.html. Retrieved 3 October 2009.
- ↑ Richard Evans (24 June 2007). "Jack the Lad". The Observer (UK). http://observer.guardian.co.uk/sport/story/0,,2110101,00.html. Retrieved 15 February 2009. "Jack Kramer 'is ready to anoint Roger Federer as the best he has seen'."
- ↑ "Federer the greatest ever — Lloyd". BBC Sport. 7 June 2009. http://news.bbc.co.uk/sport2/hi/tennis/8088191.stm. Retrieved 7 June 2009.
- ↑ Jago, Richard (5 June 2009). "'Roger Federer is the greatest' says Pete Sampras after record broken". The Guardian. London. http://www.guardian.co.uk/sport/2009/jul/05/pete-sampras-roger-federer-wimbledon. Retrieved 9 November 2010.
- ↑ Barnes, Simon (8 June 2009). "Roger Federer, greatest of all time, ensures statistics back up unrivalled artistry". The Times (UK). Archived from the original on 15 June 2020. https://web.archive.org/web/20200615062650/http://www.thetimes.co.uk/. Retrieved 9 June 2009.
- ↑ "Top 10 Men's Tennis Players of All Time". Sports Illustrated. Archived from the original on 19 September 2010. https://web.archive.org/web/20100919002329/http://sportsillustrated.cnn.com/multimedia/photo_gallery/1009/top.ten.tennis/content.1.html. Retrieved 23 September 2010.
- ↑ Federer the best of all time, says Agassi
- ↑ Federer the best of all time, says Ivan Lendl[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Roger Federer |
- Pages using duplicate arguments in template calls
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from September 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Pages using deprecated image syntax
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1981
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn ará Swítsàlandì
- Àwọn agbá tẹ́nìs ará Swítsàlandì
- Àwọn ayọrí Open Amẹ́ríkà
- Àwọn ayọrí Open Austrálíà
- Àwọn ayọrí Open Fránsì
- Àwọn ayọrí Ìdíje Wimbledon