Wọlé Sóyinká
Wọlé Sóyinká | |
---|---|
Wọlé Sóyínká ní 2018 | |
Ọjọ́ ìbí | Akínwándé Olúwolé Babátúndé Sóyíinká[1] 13 Oṣù Keje 1934 Abeokuta, Nigeria Protectorate (now Ogun State, Nigeria) |
Iṣẹ́ |
|
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Abeokuta Grammar School University of Leeds |
Ìgbà | 1957–present |
Genre |
|
Subject | Comparative literature |
Notable awards | Nobel Prize in Literature 1986 Academy of Achievement Golden Plate Award 2009 |
Akínwándé Olúwọlé Babátúndé Ṣóyínká (ọjọ́ìbí 13 July 1934) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n (Professor) nínú Ìmọ̀ Lítíréṣọ̀ (literature), alákọsílẹ̀, eré orí ìtàgé (playwright) àti akéwì (poet). Wọlé Sóyinká jẹ́ ògidì ọmọ Yorùbá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó gba Ẹ̀bùn Nobel ní ọdún 1986 fún iṣẹ́ ọwọ́ ọ rẹ̀ lórí i ìgbéga ìmọ̀ ìkọ̀wé.[2].
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Wọlé Sóyinká ní ìlú Abẹ́òkúta, ní ìpínlẹ̀ Ògùn, Lẹ́yìn tí ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní orílè-èdè Nàìjíríà àti United Kingdom tán, Ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Theatre Royal Court ni ìlú Loọ́ńdọ̀nù (London). Ó tẹ̀ síwájú láti kọ àwọn eré oníṣe lorílẹ̀ èdè méjèèjì ní tíátà àti orí ẹ̀rọ Asọ̀rọ̀-mágbèsì. Ó kó ipa pàtàkì nínú ètò ìṣèlú àti akitiyan lópọ̀lọpọ̀ nínú ìjàǹgbara òmìnira orílẹ̀ èdè Nàìjíríà kúrò lọ́wọ́ ìjọba amúnisìn Great Britain.[3]
Wole Soyinka de ko ere ti won te ni Nàìjíríà ati oke okun ,ire itagbe ati ire olori redio.Wole je eniyan paataki ninu ija ominira Naijira lati owo awon Ilu Oba.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Tyler Wasson; Gert H. Brieger (1 January 1987). Nobel Prize Winners: An H.W. Wilson Biographical Dictionary, Volume 1. The University of Michigan, U.S.A. p. 993. ISBN 9780824207564. https://books.google.com/?id=hpQYAAAAIAAJ&dq=born+Oluwole+Babatunde+Akinwande+Soyinka. Retrieved 4 December 2014.
- ↑ "The Nobel Prize in Literature 1986". NobelPrize.org. 1986-12-10. Retrieved 2019-09-19.
- ↑ Laureate., the (1934-07-13). "The Nobel Prize in Literature 1986". NobelPrize.org. Retrieved 2019-09-09.
4. Open Country Magazine. https://opencountrymag.com/52-books-in-64-years-your-guide-to-all-work-by-wole-soyinka/